-
Bibeli wipe “E mase feran aiye tabi ohun ti mbe ninu aiye. Bi enikeni ba feran aiye, ife ti Baba ko si ninu re”. I Johanu 2:15 Mo so pelu igbagbo wipe Olorun yio yo ife ohun aiye kuro lokan mi, Yio gbin ife Re si mi lokan, Yio si mu mi rin ni ona […]
-
Bibeli wipe “Bi enyin ba fe ti e si gboran, enyin o je ire ile na. Isaiah 1:19 Mo so pelu igbagbo wipe Olorun yio fun mi ni okan igboran ti yio mu mi pa ofin Re mo, emi yio si di eni ibukun ni Oruko Jesu Kristi. Amin.
-
Bibeli wipe “Nitori enyin ti je okunkun leekan, sugbon nisisiyi, enyin di imole nipa ti Oluwa: e maa rin gege bi awon omo imole” Efesu 5:8 Mo so pelu igbagbo wipe: Niwon bi Olorun ti gbami kuro lowo agbara okunkun emi yio maa rin bi omo imole ni Oruko Jesu Kristi. Amin.
-
Bibeli wipe: Nitori Oore-ofe ni a fi gba yin la nipa igbagbo; ati eyi yii ki ise ti eyin tikarayin; ebun Olorun ni kii se nipa ise, ki enikeni ma baa sogo” Efesu 2:8-9 Mo so pelu igbagbo wi pe: Olorun yio ka mi mo awon ayanfe Re, Emi ko ni so igbala ati ijoba […]
-
Bibeli wipe: “Bi enyin ba ngbe inu Mi, ti Oro Mi ba si ngbe inu nyin, e o beere ohunohun ti e ba fe, A o si see fun nyin” John 15:7 Mo so pelu igbagbo wi pe: Olorun yio fun mi loore-ofe lati gbe inu Re ati lati pa Oro Re mo, […]
-
Bibeli wipe: “E gba mi gbo pe, Emi wa ninu Baba, Baba si wa ninu mi; bikose bee, e gba mi gbo nitori awon ise naa papaa” John 14:11 Mo so pelu igbagbo wi pe: Olorun yio fi ese igbagbo mi ninu Metalokan mule, Oju ko si ni ti mi laelae, ni Oruko Jesu Kristi. […]
-
Bibeli wipe: “Sugbon eyin o gba agbara, nigbati Emi Mimo ba ba le yin: e o si maa se eleri mi ni Jerusalem ati ni gbogbo Judea, ati ni Samaria, ati titi de opin ile aye”. Ise. A. A. 1:8 Mo so pelu igbagbo wi pe: Olorun yio wo mi lakotun pelu agbara Emi Mimo […]
-
Bibeli wipe: “Nitorina O wipe, nigbati O goke lo si ibi giga, o di igbekun ni igbekun, O si fi ebun fun eniyan” Efesu 4:8 Mo so pelu igbagbo wi pe: Olorun yio fun mi ni Oore-ofe lati sawari ebun Re ninu aye mi, Un o si lo o fun idagbasoke Ijo Re, ni Oruko […]
-
Bibeli wipe: “Nitorina e maa pa eya-ara nyin ti mbe li aiye run: agbere, iwa-eeri, ifekufe, ife buburu, ati ojukokoro, ti ise iborisa”. Kol. 3:5 Mo so pelu igbagbo wi pe: Emi Mimo Olorun yio ran mi lowo lati bori ise eran ara, emi yio si di eda titun ninu Kristi, ni Oruko Jesu […]
-
Bibeli wipe: “Sugbon nigbati Oun, ani Emi Otito ni ba de yio to nyin si ona otito gbogbo, nitori ki yio so ti ara re; sugbon ohunkohun ti O ba gbo, Oun ni yio maa so: Yio si so ohun ti mbo fun yin” John 16:13 Mo so pelu igbagbo wi pe: Ëmi […]