Bibeli wipe “E mase feran aiye tabi ohun ti mbe ninu aiye.  Bi enikeni ba feran aiye, ife ti Baba ko si ninu re”.   I Johanu  2:15

Mo so pelu igbagbo wipe  Olorun yio yo ife ohun aiye kuro lokan mi, Yio gbin ife Re si mi lokan, Yio si mu mi rin ni ona iye titi opin emi mi, ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply