Bibeli wipe “Bi enyin ba fe ti e si gboran, enyin o je ire ile na.  Isaiah 1:19

Mo so pelu igbagbo wipe  Olorun yio fun mi ni okan igboran ti yio mu mi pa ofin Re mo, emi yio si di eni ibukun ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply