Bibeli wipe “Nitori enyin ti je okunkun leekan, sugbon nisisiyi, enyin di imole nipa ti Oluwa: e maa rin gege bi awon omo imole” Efesu 5:8
Mo so pelu igbagbo wipe: Niwon bi Olorun ti gbami kuro lowo agbara okunkun emi yio maa rin bi omo imole ni Oruko Jesu Kristi. Amin.