Bibeli wipe: Nitori Oore-ofe ni a fi gba yin la nipa igbagbo; ati eyi yii  ki ise ti eyin tikarayin; ebun Olorun ni kii se nipa ise, ki enikeni ma baa sogo” Efesu 2:8-9

Mo so pelu igbagbo wi pe: Olorun yio ka mi mo awon ayanfe Re, Emi ko ni so igbala ati ijoba orun nu, ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply