Bibeli wipe: “Bi enyin ba ngbe inu Mi, ti Oro Mi ba si ngbe inu nyin, e o beere ohunohun ti e ba fe, A o si see fun nyin” John 15:7

 

Mo so pelu igbagbo wi pe: Olorun yio fun mi loore-ofe lati gbe inu Re ati lati pa Oro Re mo, gbogbo ibeere mi láo muse fun mi, ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply