Bibeli wipe: “E gba mi gbo pe, Emi wa ninu Baba, Baba si wa ninu mi; bikose bee, e gba mi gbo nitori awon ise naa papaa” John 14:11

Mo so pelu igbagbo wi pe: Olorun yio fi ese igbagbo mi ninu Metalokan mule, Oju ko si ni ti mi laelae,  ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply