Bibeli wipe: “Sugbon eyin o gba agbara, nigbati Emi Mimo ba ba le yin:  e o si maa se eleri mi ni Jerusalem ati ni gbogbo Judea, ati ni Samaria, ati titi de opin ile aye”.   Ise. A. A. 1:8

Mo so pelu igbagbo wi pe: Olorun yio wo mi lakotun pelu agbara Emi Mimo Re; Emi Mimo Yio si ran mi lowo lati bori eran-ara ati lati waasu Kristi, ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply