Bibeli wipe: “Nitorina O wipe, nigbati O goke lo si ibi giga, o di igbekun ni igbekun, O si fi ebun fun eniyan” Efesu 4:8
Mo so pelu igbagbo wi pe: Olorun yio fun mi ni Oore-ofe lati sawari ebun Re ninu aye mi, Un o si lo o fun idagbasoke Ijo Re, ni Oruko Jesu Kristi. Amin.