Isotele Alafia May 20, 2022 Bibeli wipe: “Nitorina e maa pa eya-ara nyin ti mbe li aiye run: agbere, iwa-eeri, ifekufe, ife buburu, ati ojukokoro, ti ise iborisa”. Kol. 3:5 Mo so pelu igbagbo wi pe: Emi Mimo Olorun yio ran mi lowo lati bori ise eran ara, emi yio si di eda titun ninu Kristi, ni Oruko Jesu Kristi. Amin. No Comments Mr Elijah