Bibeli wipe: “Sugbon nigbati Oun, ani Emi Otito ni ba de yio to nyin si ona otito gbogbo, nitori ki yio so ti ara re; sugbon ohunkohun ti O ba gbo, Oun ni yio maa so: Yio si so ohun ti mbo fun yin” John 16:13

 

Mo so pelu igbagbo wi pe: Ëmi Mimo Olorun yio maa to mi sipa ona otito, Yio pelu mi in irinajo igbagbo mi, emi ko ni padanu ile Ologo, ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply