Bibeli wipe: “O so iji di idake-roro, bee ni riru omi re duro je. Nigbanaa ni won yo, nitori ti ara won bale, bee ni o mu won wa si ebute ife won” Ps. 107:29-30

Mo so pelu igbagbo wi pe: Agbara ajinde Jesu yio pa iji aye mi lenu mo, Yio si mu oun idiwo gbogbo si ajaga mi kuro, ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply