Bibeli wipe: “Ole kii wa bikose lati jale, ati pa, ati lati parun: Emi wa ki nwon le ni iye, ani ki nwon le nii lopolopo. Emi ni Oluso-agutan rere, Oluso-agutan rere fi emi re lele nitori awon agutan”.   John 10:10-11

Mo so pelu igbagbo wi pe: Jesu ti nse Olusoagutan rere yio pami mo ni ona mi gbogbo, ole ara ati emi ko ni ja mi, emi ko si ni bo sonu mo lowo, Un o tele titi Oun O fi mu mi de iye ainipekun, ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply