Bibeli wipe: “Tani o dabi Iwo, OLUWA, ninu awon alagbara? Tali o dabi Iwo, Ologo ni mimo, Eleru ni iyin; Ti nse ohun iyanu?” .   Exodus 15:11

 

Mo so pelu igbagbo wi pe: Olorun yio fowo agbara ajinde Re, yanju gbogbo ko seese to wa  ninu aye mi, oju ko si ni ti mi, ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply