Bibeli wipe: “Nkan wonyi ni mo ti so fun nyin tele, ki enyin ki o le ni alaafia ninu mi. Ninu aye, enyin o ni iponju, sugbon e tujuka; Mo ti segun aiye” John 16:33.
Mo so pelu igbagbo wi pe: Agbara ajinde Jesu yio fun mi ni isegun lori gbogbo ipenija mi, opin yio si de ba ibanuje ninu aye mi, ni Oruko Jesu Kristi. Amin.