Bibeli wipe: “E gba ajaga mi si orun nyin, ki e si ma ko eko lodo mi; nitori oninu tutu ati onirele okan li emi; enyin o si ri isimi fun okan nyin” Matt. 11: 29.
Mo so pelu igbagbo wi pe: Olorun yio fun mi, loore-ofe lati je onirele ati oninu tutu bi ti Jesu, ni Oruko Jesu Kristi. Amin.