Bibeli wipe  “Bi enikeni ba si dese, awa ni alagbawi lodo Baba, Jesu Kristi Olododo; oun si ni etutu fun ese wa: ki si ise fun tiwa nikan, sugbon fun ti gbogbo araiye pelu. I John 2:1-2

 

Mo so pelu igbagbo wi pe: Olorun yoo funmi ni Oore-ofe lati mo riri ise iwenumo ti Jesu se funmi, iwenumo naa ko ni jasi asan lori mi, ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply