Bibeli wipe Ki e ma si da ara yin po mo aiye yi: sugbon ki e parada lati di titun ni iro -nu nyin ki enyin ki o le ri idi ife Olorun, ti o dara, ti o si se itewogba, ti o si pe” Romu 12:2
Mo so pelu igbagbo wi pe: Emi Mimo Olorun yio sise iyipada ti o peye ninu aye mi, Emi ko si ni wa bakanna mo, ni Oruko Jesu Kristi. Amin.