Bibeli wipe, E wa sodo mi gbogbo eyin ti nsise, ti a si di eru wuwo le lorii, Emi o si fi isinmi fun nyin”  Matt. 11:28

 

Mo so pelu igbagbo wi pe: “Niwon igbati mo ti ko isoro mi to Jesu wa, Yio ba aini mi pade, Yio si fun mi ni isinmi,  ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply