Bibeli wipe “Nitorina e ronupiwada, ki e si tun yipada, ki a le pa ese nyin re, ki akoko itura ba le ti iwaju Oluwa wa. Ise A. A. 3:19
Mo so pelu igbagbo wi pe: Öluwa yio fun mi ni okan ironupiwada, eyi ti n mu idariji wa, akoko itura mi yio de , ni Oruko Jesu Kristi. Amin.