Bibeli wipe “Iwo o pa a mo li alaafia pipe, okan eniti o simi le O nitoriti o gbekele O” Isaiah 26:3

Mo so pelu igbagbo pe: Niwon igba ti mo gbeleke Olorun, Aafia pipe lati oke wa yio je ipin mi ati ti idile mi, ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply