Bibeli wipe “Ibukun ni fun gbogbo eniti o beru Oluwa; ti o si nrin li ona Re” Psalm 128:1

Mo so pelu igbagbo wipe: Iberu tooto yio gba okan mi, ese mi ko ni ye ni ona Re; Ibukun ati ire Olorun Yio si je temi, ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply