Bibeli wipe “Iwo O fi imo Re to mi si ona, ati nigbehin Iwo o gba mi sinu ogo” Psalmu 73:24

 

Mo so pelu igbagbo wipe: Olorun yio fun mi ni Imo to’peye lati bori gbogbo ipenija aye mi, Yio fi Imo Re t’omi si ona tódara, emi ko ni padanu iye ainipekun, ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply