Bibeli wipe “Temi ni imo ati ogbon ti o ye: Emi li oye, Emi li agbara.         Owe 8:14

Mo so pelu igbagbo wipe: Jesu ti nse ogbon ati agbara Olorun yio ma ko mi, yio si ma se amona mi ni ojo aye mi gbogbo,  ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply