Bibeli wipe: “Jesu na yi, ti a gba soke orun kuro lowo nyin, yio pada bee gege bi e ti rii ti o nlo si orun” Ise Awon Aposteli 1:11b

Mo so pelu Igbagbo wipe: Igbala ti mo ti ni ninu Jesu ko ni bo sonu mo mi lowo nitori naa ebi ko ni je ipin mi ni ipada bo Re li ekeji, ni Oruko Jesu Kristi.  Amin

Leave a Reply