Bibeli wipe: “Nitorina e maa sona: nitori enyin ko mo wakati ti Oluwa nyin yio de” Mattheu 24:42
Mo so pelu Igbagbo wipe: Oluwa yio fun mi ni emi ikiyesara, Yio ran mi lowo lati ma sona, ko si ni se mi ni eni egbe ni bibo Re, ni Oruko Jesu Kristi. Amin