Bibeli wipe
“Olorun; iyin duro je de o ni Sioni: ati si O li a o mu ileri ife ni se.
Iwo ti ngbo adura, si odo Re ni gbogbo eniyan nbo” Psamu 65:1-2
Mo so pelu igbagbo wipe
“Olorun ti ngbo adura yio tetisile si ebe mi, Yio si mu ife okan mi se, ni Oruko Jesu Kristi. Amin.