Uncategorized November 5, 2021 Bibeli wipe “Gbo adura mi, Oluwa, ki o si je ki igbe mi ki o wa sodo Re. Ps. 102:1 Mo so pelu igbagbo wipe “Oluwa Yio gbo adura mi, Yio si fi owo iyanu Re han ninu aye mi, Emi ko ni gbagbati adura, ni Oruko Jesu Kristi. Amin. No Comments Mr Elijah