Bibeli wipe “Kiyesii, o ti dara o si ti dun to fun awon ara lati ma jumo gbe ni irepo” Ps. 133:1

 

Mo so pelu igbagbo wipe  “Olorun yio wo Ile mi, Ijo mi, Ilu mi ati Orile-ede mi san. Yio si fun enikokan wa ni ere ati ibukun to wa ninu isokan, ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply