Bibeli wipe:
“Gbogbo eniyan yio si korira nyin nitori Oruko mi, sugbon enitio ba foriti titi fi de opin, Oun na ni a o gbala”. Matteu 10:22
Mo so pelu igbagbo wipe:
Emi-mimo yio ro mi ni agbara lati fi igbagbo pelu suru koju ipenija aye mi titi un o fi di asegun ni Oruko Jesu Kristi. Amin.