Bibeli wipe “Nitori a ti pe nyin si omnira, ara; kiki pe ki e mase lo omnira nyin fun aye sipa ti ara, sugbon e maa fi ife sin omonikeji nyin”Galatians  5:13.

 

Mo so pelu igbagbo wipe: Olorun yio fun mi ni emi ati agbara lati sin I nipa sisin omonikeji mi, emi ko ni padanu ere ijoba orun ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply