Bibeli wi pe “Emi ni Olorun, awon eni ti nsin in, ni lati sin ni emi ati otito”  John 4:24

 

 

Mo so pelu igbagbo wi pe:

Olorun yio ran mi lowo nipa agbara Emi Mimo lati sin I ni emi ati ni otito,  ise isin mi yio si je itewogba niwaju Re ni Oruko Jesu Kristi. Amin.

Leave a Reply