Bibeli wi pe “Ojo Oluwa ku si dede, o ku si dede, o si nyara kankan, ani ohun ojo Oluwa: alagbara okunrin yio sokun kikoro nibe”  Zeph. 1:14

Mo so pelu igbagbo wi pe:

Emi ko ni sokun kikoro ni aye yi ati pelupelu ni ipadabo Re, ni Oruko Jesu Kristi. Amin.

Leave a Reply