Bibeli wi pe “Nitorina emi onde ninu Oluwa mbe yin pe ki eyin ki o maa rin bi o ti ye fun ipe na ti a fi pe nyin”.  Efesu 4:1

 

 

Mo so pelu igbagbo wi pe: “Olorun yoo fun mi ni Oore-ofe lati rin ni pipe ninu ipe mi gegebi Kristiani, ni Oruko Jesu Kristi. Amin

Leave a Reply