Bibeli wi pe “Bi eyin ba fe ti e si gboran, eyin o je ire ile naa”. Isa. 1:19

Mo so pelu igbagbo wi pe: “Olorun yoo fun mi ni eti igbo ati aya igbase si gbogbo ofin Re, Emi ati ebi mi yoo ri oju rere Re gba ni Oruko Jesu Kristi”.   Amin

Leave a Reply