Bibeli wipe “Jesu wi fun un pe, Emi ko ti wi fun o pe, bi iwo ba gbagbo, iwo o ri ogo Olorun”  Johannu  11:40

Mo so pelu igbagbo wipe: “Olorun yio mu igbagbo mi jinle ninu Re, Emi ati ebi mi yio ri Ogo Olorun ni Oruko Jesu Kristi.   Amin

Leave a Reply