Bibeli wipe “Ofin yii ni awa si ri gba lati owo re wa, pe eni ti o ba feran Olorun ki o feran arakunrin re pelu” I Johannu 4:21
Mo so pelu igbagbo wipe “Olorun yio fun mi ni Emi Mimo Re lati feran Re ati Omonikeji mi, ise isin mi ko ni jasi asan ni Oruko Jesu Kristi. Amin