Bibeli wipe “Ibukun ni fun eni ti nro ti awon alaini Oluwa yoo gba a ni igba iponju” Psaamu 41:1
Mo so pelu igbagbo wipe “Olorun yio funmi l’oore-ofe lati maa ran awon alaini lowo; iranlowo lati oke wa ati anu Olorun yo ma je ipin mi ni ojo aye mi gbogbo ni Oruko Jesu Kristi. Amin