Bibeli wipe “Nipa eyi ni gbogbo eniyan yoo fi mo pe, omo-ehin mi ni eyin je, nigbati eyin ba ni ife si ara yin” John 13:35
Mo so pelu igbagbo wipe “Olorun yio funmi ni ebun ife ti o ga julo lati feran Ree, ati omonikeji mi, ki n ba le je Omo-ehin tooto ni Oruko Jesu Kristi. Amin