Bibeli wipe “Bi emi ba  gba ese ni aya mi Oluwa ki yio gbohun mi”

Orin Dafidi  66:18

Mo so pelu igbagbo wipe “Olorun yio fun mi ni oore-ofe lati yera fun ohunkohun ti yio dena adura mi, emi yio gba agbayori adura,  ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply