Bibeli wipe
“Nitori naa bi enikeni ba wa ninu Kristi, o di eda titun; ohun atijo ti koja lo; kiyesii, ohun gbogbo di titun” II Kor. 5:17
Mo so pelu igbagbo wipe
“Olorun yio so mi di eda titun ninu Kristi nipa Emi Mimo, Emi yio maa rin ni ona Re ni Oruko Jesu Kristi. Amin.