Bibeli wipe “Bi awa ba jewo ese wa, Olooto ati Olododo ni Oun lati dari ese wa ji wa, ati lati we wa nu kuro ninu aisidodo gbogbo” I John 1:9

 

Mo so pelu igbagbo wipe “Olorun  yio fun mi ni Emi ironupinuwada ati  idariji ese mi, Yio so mi d’eda titun nipa isodimimo ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply