Bibeli wipe,

“Sugbon Olorun mi yoo pese ni kikun fun gbogbo aini yin, gege bi oro re ninu ogo ninu Kristi Jesu” Filippi 4:19

Mo so pelu igbagbo wipe,

“Olorun ninu aanu Re yoo pese ni kikun fun aini t’ara ati t’emi mi, emi ki yii se alaini ohun t’o dara ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply