Bibeli wipe: “Je ki eniyan maa ka wa bee bi iranse Kristi ati Iriju awon ohun ijinle Olorun ”

I Cor. 4:1

 

Mo so pelu igbagbo wipe:

Olorun yio ran mi lowo nipa Emi Mimo lati se ohun ti o wu U, l’oro ati nise ni Oruko Jesu Kristi.   Amin.

Leave a Reply