Bibeli wipe: “Yi oju mi kuro lati ma wo ohun asan, mu mi ye li ona re”

Ps. 119:37

 

Mo so pelu igbagbo wipe:

Olorun yio yi oju mi kuro lati ma wo ohun asan aye yi, Yio fi ife Re s’okan mi fun ire mi ni Oruko Jesu Kristi.   Amin.

Leave a Reply