Bibeli wipe: “Ko le si Juu tabi Griki, eru tabi ominira, okunrin tabi obinrin nitori pe okan ni gbogbo yin je ninu Kristi Jesu” Gal. 3:28
Mo so pelu igbagbo wipe: Olorun yio fun mi ni Oore-ofe lati se ohun ti yio mu isokan ara Kristi mule, fun ogo Oruko Re ni Oruko Jesu Kristi . Amin