Bibeli wipe ”Iwo o pa a mo li alaafia pipe, okan eniti o simi le O: nitoriti o gbekele O” Isaiah 26:3

 

Niwon igbati mo ti fi gbekele mi sinu Olorun. Mo so pelu igbagbo pe: Buburu kan ki yio subu lu mi, arunkarun ki yio sumo ago mi, ni Oruko Jesu Kristi Oluwa wa.  Amin.

 

Leave a Reply