Bibeli wipe ”Olufe, emi ngbadura pe ninu ohun gbogbo ki o le ma dara fun o, ki o si maa wa ni ilera, ani bi o ti dara fun okan re”. 3 John 2

 

Mo so pelu igbagbo pe: Aisan ko ni ri ibi gbe ninu ago ara mi, emi yo wa ni ilera, yio o si dara fun mi bi okan mi ti nfe, ni Oruko Jesu Kristi.  Amin.

Leave a Reply