Bibeli wipe ”Jesu si wi fun gbogbo won pe, Bi enikan ba nfe lati ma a to mi lehin, ki o se ara re, ki o si gbe agbelebu re ni ojo gbogbo, ki o si maa to mi lehin”

 

Mo so pelu igbagbo pe “Olorun yio ro mi ni agbara ti nfi aya ran isoro ti si nbori won ati ti nbori ipenija gbogbo,

ni Oruko Jesu Kristi. Amin.

Luku 9:23

Leave a Reply