Bibeli wipe ”Sugbon a saa li ogbe nitori irekoja wa, a paa li ara nitori aisedede wa; ina alafia wa wa lara Re, ati nipa ina Re li a fi mu wa lara da” Isa.53:5

 

Mo so pelu igbagbo wipe “Gbogbo ibukun ti o ti inu iya, iku ati ajinde Jesu wa, yio je temi ati idile mi ni Oruko Jesu Kristi. Amin.

 

Leave a Reply